Full Lyrics
INTRO
Ogo!
Ọba awọn'ba, Ọlọrun rere,
Ọba ogo gb'ọpẹ wa.
O fun mi ni orin; Ogo!
CHORUS
O! Ẹ yin Oluwa l'ogo!
Ẹ yin Oluwa l'ogo!
Ẹ yin Oluwa l'ogo!
Ẹ yin Oluwa l'ogo!
Ọba idariji,
Ọba giga,
A dupẹ o Baba,
Awa n yin o l'ogo.
Aiye o.
VERSE 1
Ni igbati nkan da, Oluwa wa pẹlu mi.
Ni igbati gbogbo nkan le, Oluwa wa pẹlu mi.
O fun mi ni orin ti mo le kọ,
Ti ma lulu fun, ti ma jo si!
Oluwa wa pẹlu mi.
Oluwa wa pẹlu mi.
Ah! Ọba awọn' ba,
Baba ẹse!
Tori ẹ ni mo ṣe n sọ!
VERSE 2
Ọba! Ogo!
Baba! Ẹse o!
Ọba! Ogo!
Baba! Ẹse o!
Ọba! Ogo!
Ọba ẹse o, Ọba! Ogo!
Ọba ẹse, Ọba awọn' ba! Ah!
Ọba mimọ, Ọba to to,
Ọba giga giga giga giga, Ọba aye!
Ṣe o! Ọba Oyigiyigi!
Aribitirabata!
Awimayehun!
Alewilese!
Ọba! Eh!
Ogo! Eh!
Kabiyesi o!
Atofarati!
Jagunjagun ọdẹ ọrun!
Eledumare!
Atobijulọ!
Ogo! Ẹse o! Ọba! Ogo!
Ẹse o, Ọba! Ogo!!
CHORUS
Eh! Ẹ yin Oluwa l'ogo!
Ẹ yin Oluwa l'ogo!
Ẹ yin Oluwa l'ogo!
Ẹ yin Oluwa l'ogo!
L'ogo! Ẹ yin Oluwa l'ogo!
Ẹ yin Oluwa l'ogo!
Ọba idariji,
Ọba giga,
A dupẹ o Baba,
Awa n yin o l'ogo.
Ẹ yin Oluwa,
Oh! Ọba!
Oh! Ọba!
Oh! Ọba,
Ogo!!