Full Lyrics
VERSE 1
Mo jẹ Baba l'ọpẹ,
Mo jẹ Baba l'ọpẹ,
Mo jẹ Baba l'ọpẹ o,
Mo jẹ Baba mi o l'ọpẹ.
CHORUS
Nigbati mo ro
Iṣẹ iyanu,
Baba mi o, Baba
L'aye mi o,
Mo ri wipe
Mo jẹ Baba mi l'ọpẹ o.
VERSE 2
Ma fun Baba l'ọpẹ,
Ma fun Baba l'ọpẹ,
Ma fun Baba l'ọpẹ o,
Ma fun Baba mi o l'ọpẹ.
VERSE 3
Ma fun Baba l'aye,
Ma fun Baba l'aye,
Ma fun Baba l'aye o,
Ma fun Baba l'aye mi o.