MIMO OLUWA by Sam O. Ezugwu — Lyrics

Sam O. Ezugwu Yoruba Sanctus (Holy, Holy, Holy) Solfa notation

Full Lyrics

Mímọ́, mímọ́, mímọ́, mímọ́, mímọ́, Mímọ́ Olúwa, Ọlọ́run alágbára ńlá, ayé àti ọ̀run kún fún ìyìn rẹ̀. Hòsánà, Hòsánà, Hòsánà lókè Ọ̀run. Alábùkún ni fún ẹni tó wá ní orúkọ Olúwa, ní orúkọ Olúwa.

Download the sheet music

MIMO OLUWA

MIMO OLUWA

By Sam O. Ezugwu
Solfa
Yoruba
1 page
4 Downloads
Sanctus (Holy, Holy, Holy)
0 0

More lyrics you may want