SANCTUS Mimo L'oluwa by Charles Onwubuya — Lyrics

Charles Onwubuya Yoruba Sanctus (Holy, Holy, Holy) Solfa notation

Full Lyrics

CHORUS Mimo! Mimo! Mimo L'oluwa Olorun awon omo ogun Olorun awon omo ogun oh! Mimo! Olorun awon omo ogun ah! VERSE 1 Orun oun aye kun fun ogo re ye o! oh! Hosanna lo ke orun Ibukun ni feni t'on bo wa l'oruko Oluwa Hosanna lo ke orun Mimo! Mimo! Mimo! oh VERSE 2 Hosanna, Hosanna Hosanna, Hosanna Hosanna lo ke orun Hosanna Hosanna, Hosanna, Hosanna

Download the sheet music

SANCTUS Mimo L'oluwa

SANCTUS Mimo L'oluwa

By Charles Onwubuya
Solfa
Yoruba
2 pages
12 Downloads
Sanctus (Holy, Holy, Holy)
0 0

More lyrics you may want