Full Lyrics
Mimọ, mimọ, mimọ, mimọ
Mimọ, mimọ, mimọ, mimọ
L'Oluwa! Ọlọrun awọn ọmọ ogun,
ọrun oun aye kun fun ogo Rẹ.
Hosana l'oke ọrun, hosana l'oke ọrun,
Hosana l'oke ọrun! l'oke! ọrun!
L'Oluwa! Ibukun ni fun ẹni t'o nbọ wa,
l'orukọ Oluwa!
Hosana l'oke ọrun, hosana l'oke ọrun,
Hosana l'oke ọrun! l'oke! ọrun!
L'Oluwa!