Full Lyrics
VERSE 1
Iye ti a ni, ti Baba ni;
Baba l'o fi fun wa.
Aabo ti a ni, ti Baba ni;
Baba l'o fi fun wa.
CHORUS
Ohun ti a fi n s'aye,
odo Re l'o ti wa.
Ose o Baba!
Baba, ope ye O.
VERSE 2
Owo ti a ni, ti Baba ni,
Baba l'o fi fun wa.
Ona ti a fi nlo'gba,
Baba l'o fi fun wa.
VERSE 3
Omo ti a bi, ti Baba ni,
Baba l'o fi fun wa.
Oye at'imo ti a ni, ti Baba ni,
Baba l'o fi fun wa.
VERSE 4
Gbogbo ire ti a ni, ti Baba ni,
Baba l'o fi fun wa.
Ooreofe Oluwa,
iyen ma n ba wa gbe repete.