MIMO MIMO MIMO by Abraham I. Inetiabor — Lyrics

Abraham I. Inetiabor Yoruba Sanctus (Holy, Holy, Holy) Staff & Solfa notation

Full Lyrics

Mímọ́ mímọ́ mímọ́ l'Oluwa, Ọlọrun awọn ọmọ ogun o. Mímọ́ mímọ́ mímọ́ l'Oluwa, Ọlọrun awọn ọmọ ogun o. Ọrun oun aye kun fun ogo rẹ. Mímọ́ l'Oluwa. Hosanna loke ọrun. Ibukun ni f'ẹni to n bọ wa L'orukọ Oluwa. Mímọ́ l'Oluwa. Hosanna loke ọrun.

Download the sheet music

MIMO MIMO MIMO

MIMO MIMO MIMO

By Abraham I. Inetiabor
Staff & Solfa
Yoruba
3 pages
1 Downloads
Sanctus (Holy, Holy, Holy)
0 0

More lyrics you may want