Full Lyrics
VERSE 1
Alabukun ni fun iwọ, Oluwa Ọlọrun gbogbo ẹda
Ọpẹ ni fun oore Rẹ, akara yii ti a mu wa:
Eso ile, isẹ ọwọ wa,
Yoo di ounjẹ iyè.
CHORUS
Ibukun ni fun Ọlọrun,
Ibukun ni fun Ọlọrun,
titi laelae. Amin.
VERSE 2
Alabukun ni fun iwọ, Oluwa Ọlọrun gbogbo ẹda
Ọpẹ́ ni fun oore Rẹ, ọti yii ti a mu wa:
Eso ajara, isẹ ọwọ wa,
Yoo di ife igbala wa.
VERSE 3
Alabukun ni fun iwọ, Oluwa Ọlọrun gbogbo ẹda
Ọpẹ ni fun oore Rẹ, a pese ara wa:
Iyọ aye, isẹ ọwọ rẹ,
A gbadura lati di isokan laye ainipẹkun.