Full Lyrics
[REFRAIN]
Gba a lọwọ mi o Baba (Gba a)
Gba a lọwọ mi o Baba (Gba a)
Gba a lọwọ mi o Baba (Gba a)
Gba a lọwọ mi o Baba
Gb'ọrẹ atinuwa mi o (Gb'ọrẹ)
Gb'ọrẹ atọkanwa mi o (Gb'ọrẹ)
Ohun ti mo mu wa fun o ree o
Gba a lọwọ mi o Baba (Gba a)
[VERSE 1]
Baba to da mi si d'oni o
Ọpẹ ni fun o o Baba
Ọpẹ iyin lo yẹ fun o
Ọba ologo julọ wa gba gb'ọrẹ
Ti mo mu wa fun o o
Gba a lọwọ mi o Baba (Gba a)
[VERSE 2]
Gba a lọwọ mi o Baba
Gba a lọwọ mi o Baba
Ọrẹ bii ti Abẹli
Gba a lọwọ mi o Baba
Ọrẹ atọkanwa mi
Gba a lọwọ mi o Baba
Ọrẹ to dara to dẹrù
Gba a lọwọ mi o Baba (Gba a)