Full Lyrics
SOLO
Baba mimo a de, awa siwaju re
Baba mimo a de, a wa le fun O
Baba mimo a de, a tun wa juba re, dari ese wa ji
CHORUS
Oba Olum'ona
Gba adura wa
Dariji wa o
Oba Olupese
Baba
Ran Emi mimo re si wa
Wa sinu gbogbo wa k'o to wa sona
Sokale wa
Baba mimo
Gbo adura wa
Wa f'ase si Baba
Mo f'ase si Baba mimo k'adura mi gba l'oruko Jesu
Amin o
Amin o