Full Lyrics
Amore amore Baba a m'ore
Amore amore Baba a m'ore Baba wa
CHORUS
Iyin to si Baba l'oke
Iyin to si Eledumare
Iyin l'o yẹ Baba gb'ọpẹ
Iyin l'o yẹ Baba gb'ọpẹ
Iyin l'o yẹ Onibu ọrẹ
Baba adupẹ o a m'ore
Baba adupẹ o a m'ore Baba wa
A m'ore a m'ore a m'ore a m'ore
Baba a m'ore Baba a m'ore Baba a wa
A m'ore a m'ore Oloore Onibu ọrẹ a m'ore
Ọrẹ ọfẹ rẹ a m'ore a m'ore
Ẹ ṣe a m'ore a m'ore ẹ ṣe a m'ore a m'ore ẹ ṣeun o
A m'ore a m'ore ẹ ṣe a m'ore a m'ore ẹ ṣe a m'ore a m'ore
Ẹ ṣeun o ẹ ṣe adupẹ o Baba adupẹ Baba Baba wa
OSTINATO
Ọba yẹ Ọba yẹ Ọba yẹ Ọba yẹ
Awi mayẹhun iba rẹ rẹ
TENOR SOLO
Onibu ọrẹ Ẹlẹdumare ọba
Ẹyin lẹ ṣe yi tan a wa dupẹ o
Ifẹ Rẹ l'aiye wa o ma pọ o
SOPRANO SOLO
Wa gb'ọpẹ wa gb'ọpẹ Baba wa gb'ọpẹ
Adupẹ Baba a m'ore o fẹ
A m'ore adupẹ o
CHORUS
Ọba yẹ Ọba yẹ Ọba yẹ Ọba yẹ
Awi mayẹhun iba rẹ rẹ
Iba rẹ rẹ iba rẹ rẹ Baba wa gb'ọpẹ wa
DUET
Fun oore fun oore
Ah ọpẹ yẹ Baba iyin a t'ọpẹ
Yẹ Baba iyin a t'ọpẹ
Yẹ Baba iyin a t'ọpẹ
Yẹ Baba iyin a t'ọpẹ
Fun oore a m'ore o Baba fun o Baba
Iyin a t'ọpẹ yẹ Baba iyin a t'ọpẹ
Yẹ Baba iyin a t'ọpẹ
Yẹ Baba iyin a t'ọpẹ
Yẹ Baba iyin a t'ọpẹ
Yẹ Baba Baba adupẹ o a m'ore
Baba adupẹ o a m'ore
Baba adupẹ a m'ore