Alade Ogo 'Gbope by Obum Edward I — Lyrics

Obum Edward I Yoruba Offertory Hymns Hymns Celebrations Solfa notation

Full Lyrics

Iyin a! o yẹ o Baba Ọba Iye Iyin a! o yẹ o Ọlọrun o Ọba mimọ wa ẹ pe ẹ wa ẹ wa ẹ wa Alade ogo gbọpẹ ẹrọ wa Ọlọrun iye gbọpẹ wa Alade Ogo Adupẹ fun ohun gbogbo ti ẹ ti ṣe Adupẹ ṣe a'n yin o pe Ọba mimọ Ọlọrun gbogbo aye Baba dakun gbọpẹ wa Alade Ogo Gbọpẹ Olore Alade Ogo gbọpẹ wa Kabiyesi Ọba mimọ Olu moro Ọba rere Awimayẹhun gbọpẹ wa Alade Ogo Gbọpẹ Baba jọwọ gbọpẹ wa Adupẹ Baba Awimayẹhun Baba Adupẹ o Baba ẹ ṣe o Baba Awimayẹhun Baba ẹ ṣe o Baba adupẹ Mimọ o Baba atobiju lọ Adupẹ Ṣe iye wa o Ọba mimọ Awimayẹhun Baba Olupese ọpẹ wa Ọba oye ka ye o Ọba nla Kabiyesi Iwọ lo pa ye Iwọ lo ba iye Ọba igba Ọba nla nla nla, Ọba nla nla nla Ọba nla nla nla mimọ Baba jọwọ gbọpẹ wa Baba Ọpẹ yẹ o Baba Ọpẹ yẹ o Baba Olodumare Ọba ogo Ọpẹ yẹ o Baba Ọpẹ yẹ o Baba Adupẹ o Baba Alade Ogo Alade Ogo Alade Ogo Edumare dakun jọwọ Ọpẹ yẹ o

Download the sheet music

Alade Ogo 'Gbope

Alade Ogo 'Gbope

By Obum Edward I
Solfa
Yoruba
5 pages
2 Downloads
Offertory Hymns Hymns Celebrations
0 0

More lyrics you may want