Full Lyrics
REFRAIN
Ab'ore Oluwa, Ojise Olodumare,
Ipo elege mani o,
Iwa mimo ni ki e maa wu,
K'ebo le fin o, k'ebo le gba.
VERSE 1
Opo l'ape eyin ara mi,
Ore ofe t'ogaju ni eyi o,
Ebun Olorun ni a fi fun o,
Yara loo b'o se ye.
VERSE 2
Apewon o lati t'aiye se,
K'on ru'bo nitori ese ni o,
Agbara won ko l'on fi n s'ise yen,
K'ebo le da o d'owo Olorun.