Omo Maria Ku Fun' WA by Sir Adajoh John — Lyrics

Sir Adajoh John Yoruba Marian Hymns Lenten Hymns Entrance songs Communion Hymns Holy Week Hymns Solfa notation

Full Lyrics

REFRAIN Ah, ọma ṣe, ọma ṣe, Ọmọ Maria ku fun wa. Ku nitori wa, iku ṣe tan, ọma ṣe. Ọmọ Maria ku fun wa. San igbese, iku ṣe tan, Iku doro, ọma ṣe, Ọmọ Maria ku fun wa. VERSE 1 Jiya fun ẹṣẹ, awa lo to si o, fun ẹṣẹ rẹ. Gbogbo iya to jẹ, awa lo to si o. VERSE 2 O le iku wọ gbo nitori wa. O wi pe o ti pari, o ti pari.

Download the sheet music

Omo Maria Ku Fun' WA

Omo Maria Ku Fun' WA

By Sir Adajoh John
Solfa
Yoruba
1 page
2 Downloads
Marian Hymns Lenten Hymns Entrance songs Communion Hymns Holy Week Hymns
1 0

More lyrics you may want